Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

●○○NÍGBÀ ÀKỌ́KỌ́

Ìbéèrè: Báwo la ṣe lè mọ ohun tó máa ṣẹlẹ̀ lọ́jọ́ iwájú?

Bíbélì: Ais 46:10

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Kí ni Ọlọ́run sọ pé òun máa ṣe fún àwa èèyàn àti ilẹ̀ ayé lọ́jọ́ iwájú?

○●○ ÌPADÀBẸ̀WÒ ÀKỌ́KỌ́

Ìbéèrè: Kí ni Ọlọ́run sọ pé òun máa ṣe fún àwa èèyàn àti ilẹ̀ ayé lọ́jọ́ iwájú?

Bíbélì: Sm 37:29

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Kí ló yẹ ká ṣe tá a bá fẹ́ gbádùn ìlérí ọjọ́ iwájú tí Bíbélì sọ?

○○● ÌPADÀBẸ̀WÒ KEJÌ

Ìbéèrè: Kí ló yẹ ká ṣe tá a bá fẹ́ gbádùn ìlérí ọjọ́ iwájú tí Bíbélì sọ?

Bíbélì: Sm 37:34

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Irú ìgbésí ayé wo ni Ọlọ́run fẹ́ ká máa gbé?