Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

May 28–​June 3

MÁÀKÙ 13-14

May 28–​June 3
  • Orin 55 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • Má Ṣe Jẹ́ Kí Ìbẹ̀rù Èèyàn Dẹkùn Mú Ẹ”: (10 min.)

    • Mk 14:​29, 31​—Kì í ṣe pé àwọn àpọ́sítélì fẹ́ kọ Jésù sílẹ̀

    • Mk 14:50​—Nígbà tí wọ́n mú Jésù, gbogbo àwọn àpọ́sítélì pa Jésù tì, wọ́n sì sá lọ

    • Mk 14:​47, 54, 66-72​—Pétérù nígboyà láti gbèjà Jésù, ó tẹ̀ lé e ní òkèèrè réré, àmọ́ nígbà tó yá, ó da Jésù ní ìgbà mẹ́ta (ia 200 ¶14; it-2 619 ¶6)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Mk 14:​51, 52​—Ta ló ṣeé ṣe kí ọ̀dọ́kùnrin tó sá lọ ní ìhòòhò náà jẹ́? (w08 2/15 30 ¶6)

    • Mk 14:​60-62​—Kí ló ṣeé ṣe kó jẹ́ ìdí tí Jésù fi dáhùn ìbéèrè àlùfáà àgbà náà? (jy 287 ¶4)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Mk 14:​43-59

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Ìpadàbẹ̀wò Kejì: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Pe ẹni náà wá sí ìpàdé.

  • Ìpadàbẹ̀wò Kẹta: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ìwọ ni kó o yan ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tó o máa lò. Fi ọ̀kan nínú àwọn ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ lọ̀ ọ́.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh 171-172 ¶17-18

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI