Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | MÁÀKÙ 13-14

Má Ṣe Jẹ́ Kí Ìbẹ̀rù Èèyàn Dẹkùn Mú Ẹ

Má Ṣe Jẹ́ Kí Ìbẹ̀rù Èèyàn Dẹkùn Mú Ẹ

Kí nìdí tí àwọn àpọ́sítélì fi jẹ́ kí ìbẹ̀rù èèyàn mú wọn?

14:29, 31

  • Wọ́n dá ara wọn lójú jù. Pétérù tiẹ̀ tún ronú pé òun máa dúró ti Jésù ju àwọn àpọ́sítélì tó kù lọ

14:32, 37-41

  • Wọn ò wà lójúfò, wọn ò sì gbàdúrà

Lẹ́yìn tí Jésù jíǹde, kí ló ran àwọn àpọ́sítélì tó ti ronú pìwà dà yìí lọ́wọ́ láti má ṣe jẹ́ kí ìbẹ̀rù èèyàn dẹkùn mú wọn, tí wọ́n sì ń wàásù láìka àtakò sí?

13:9-13

  • Wọ́n fi ìkìlọ̀ Jésù sọ́kàn, torí náà wọ́n ti wà ní ìmúrasílẹ̀ fún àtakò tàbí inúnibíni

  • Wọ́n gbára lé Jèhófà, wọ́n sì ń gbàdúrà.​—Iṣe 4:​24, 29

Irú ipò wo ló lè dán ìgboyà wa wò?