Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

May 7-​13

MÁÀKÙ 7-8

May 7-​13
  • Orin 13 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • Gbé Òpó Igi Oró Rẹ, Kí Ó sì Máa Tọ̀ Mí Lẹ́yìn”: (10 min.)

    • Mk 8:34​—Ká tó lè tẹ̀ lé Kristi, a gbọ́dọ̀ sẹ́ níní ara wa (“kí ó sẹ́ níní ara rẹ̀” àlàyé ọ̀rọ̀ lórí Mk 8:34 nwtsty; w92 8/1 17 ¶14)

    • Mk 8:​35-37​—Jésù béèrè àwọn ìbéèrè méjì tó ń múni ronú jinlẹ̀ tó máa jẹ́ ká mọ ohun tó yẹ ká fi sípò àkọ́kọ́ nígbèésí ayé wa (w08 10/15 25-26 ¶3-4)

    • Mk 8:38​—A nílò ìgboyà tá a bá fẹ́ tẹ̀ lé Kristi (jy 143 ¶4)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Mk 7:​5-8​—Kí ló dé táwọn Farisí fi ranrí mọ́ ọ̀rọ̀ fífọ ọwọ́? (w16.08 30 ¶1-4)

    • Mk 7:32-35​—Báwo ni bí Jésù ṣe fi ẹ̀mí ìgbatẹnirò hàn sí ọkùnrin adití náà ṣe jẹ́ àpẹẹrẹ fún wa? (w00 2/15 17-18 ¶9-11)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Mk 7:​1-15

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI