Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | MÁÀKÙ 7-8

Gbé Òpó Igi Oró Rẹ, Kí Ó sì Máa Tọ̀ Mí Lẹ́yìn

Gbé Òpó Igi Oró Rẹ, Kí Ó sì Máa Tọ̀ Mí Lẹ́yìn

8:34

Jésù sọ pé: “Máa tọ̀ mí lẹ́yìn nígbà gbogbo.” Torí náà, ó yẹ ká máa fara dà á nìṣó. Báwo lo ṣe lè máa sapá láti tẹ̀ lé Jésù tó bá kan ọ̀rọ̀ . . .

  • àdúrà?

  • ìkẹ́kọ̀ọ́?

  • iṣẹ́ ìwàásù?

  • lílọ sí ìpàdé?

  • dídáhùn ní ìpàdé?