June 14-20
DIUTARÓNÓMÌ 5-6
Orin 134 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Kọ́ Ọmọ Rẹ Kó Lè Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà”: (10 min.)
Àwọn Ìṣúra Tẹ̀mí: (10 min.)
Di 5:21—Kí ni òfin tí Jèhófà ṣe lórí ojúkòkòrò kọ́ wa? (w19.02 22 ¶11)
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min.) Di 5:1-21 (th ẹ̀kọ́ 5)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Fi ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì lọ ẹni náà, kó o sì ṣe bíi pé ẹ wo fídíò Báwo La Ṣe Máa Ń Ṣe Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì? (àmọ́ ẹ má ṣe wò ó) (th ẹ̀kọ́ 9)
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Sọ ohun tó máa bá ipò onílé mu, kó o sì ka ẹsẹ Bíbélì tó máa wọ̀ ọ́ lọ́kàn. (th ẹ̀kọ́ 12)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min.) fg ẹ̀kọ́ 9 ¶6-7 (th ẹ̀kọ́ 8)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Máa Fìfẹ́ Hàn Nínú Ìdílé”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Máa Fi Ìfẹ́ Ti Kì Í Yẹ̀ Hàn Nínú Ìdílé.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 9 ¶27-32, àpótí 9D àti 9E
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 111 àti Àdúrà