Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Kọ́ Ọmọ Rẹ Kó Lè Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà

Kọ́ Ọmọ Rẹ Kó Lè Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà

Àwọn òbí gbọ́dọ̀ kọ́kọ́ nífẹ̀ẹ́ Jèhófà (Di 6:5; w05 6/15 20 ¶11)

Wọ́n gbọ́dọ̀ fi àpẹẹrẹ tó dáa lélẹ̀ fáwọn ọmọ wọn (Di 6:6; w07 5/15 15-16)

Wọ́n gbọ́dọ̀ máa kọ́ àwọn ọmọ nípa Jèhófà léraléra (Di 6:7; w05 6/15 21 ¶14)

Yàtọ̀ sígbà tẹ́ ẹ bá ń ṣe ìjọsìn ìdílé, àwọn ìgbà wo lo tún lè kọ́ àwọn ọmọ rẹ kí wọ́n lè nífẹ̀ẹ́ Jèhófà àtàwọn ìlànà rẹ̀?