June 7-13
DIUTARÓNÓMÌ 3-4
Orin 98 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Àwọn Òfin Jèhófà Bọ́gbọ́n Mu, Wọ́n sì Bá Ìdájọ́ Òdodo Mu”: (10 min.)
Àwọn Ìṣúra Tẹ̀mí: (10 min.)
Di 4:23—Ṣé ohun tí ẹsẹ yìí ń sọ ni pé ó burú káwọn ọmọ Ísírẹ́lì gbẹ́ ère láti fi ṣe ọ̀ṣọ́? (w04 9/15 25 ¶3)
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min.) Di 3:1-13 (th ẹ̀kọ́ 10)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
“Jẹ́ Kí Iṣẹ́ Sísọni Di Ọmọ Ẹ̀yìn Máa Fún Ẹ Láyọ̀—Máa Lo Ìtara Tó O Bá Ń Kọ́ni”: (10 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Jẹ́ Kí Iṣẹ́ Sísọni Di Ọmọ Ẹ̀yìn Máa Fún Ẹ Láyọ̀—Túbọ̀ Já Fáfá—Máa Lo Ìtara Tó O Bá Ń Kọ́ni.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min.) fg ẹ̀kọ́ 5 ¶1-2 (th ẹ̀kọ́ 11)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (15 min.)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 9 ¶18-26, àpótí 9A àti 9B
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 110 àti Àdúrà