Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

May 10-16

NỌ́ŃBÀ 30-31

May 10-16
  • Orin 51 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • San Ẹ̀jẹ́ Rẹ”: (10 min.)

  • Àwọn Ìṣúra Tẹ̀mí: (10 min.)

    • Nọ 30:10-12​—Báwo la ṣe mọ̀ pé Ẹlikénà fọwọ́ sí i bí Hánà ṣe jẹ́jẹ̀ẹ́ pé òun máa yọ̀ǹda kí Sámúẹ́lì fayé ẹ̀ sin Jèhófà? (1Sa 1:11; it-2 28 ¶1)

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min.) Nọ 30:1-16 (th ẹ̀kọ́ 5)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 5

  • Kọ́ Ìfaradà Lára Àwọn Ohun Tí Ọlọ́run Dá: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà. Lẹ́yìn náà, bi àwọn ará ní ìbéèrè méjì yìí lórí ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn ewéko àtàwọn ẹranko tí wọ́n rí nínú fídíò náà. Kí ló fi hàn pé ó ní ìfaradà? Báwo làwa náà ṣe lè fìwà jọ ọ́?

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 8 ¶16-22

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)

  • Orin 4 àti Àdúrà