Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àwọn ọmọbìnrin Sélóféhádì béèrè fún ogún bàbá wọn

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Yẹra fún Ojúsàájú, Kó O Lè Fìwà Jọ Jèhófà

Yẹra fún Ojúsàájú, Kó O Lè Fìwà Jọ Jèhófà

Àwọn ọmọbìnrin Sélóféhádì márùn-ún fẹ́ gba ogún bàbá wọn (Nọ 27:​1-4; w13 6/15 10 ¶14; wo àwòrán iwájú ìwé)

Ìpinnu tí Jèhófà ṣe fi hàn pé kì í ṣe ojúsàájú (Nọ 27:5-7; w13 6/15 11 ¶15)

Àwa náà gbọ́dọ̀ yẹra fún ojúsàájú (Nọ 27:8-11; w13 6/15 11 ¶16)

Tá a bá ń fìfẹ́ hàn sáwọn ará wa, tá à ń bọ̀wọ̀ fún wọn, tá a sì ń wàásù fún onírúurú èèyàn láìka ibi tí wọ́n ti wá sí, ṣe là ń fi hàn pé a kì í ṣe ojúsàájú, àá sì máa fìwà jọ Jèhófà.