Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Má Ṣe Gba Èròkerò Láyè

Má Ṣe Gba Èròkerò Láyè

Dáfídì gba èròkerò láyè nínú ọkàn rẹ̀ (2Sa 11:2-4; w21.06 17 ¶10)

Dáfídì lo agbára àti ọlá àṣẹ tó ní láti bo ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ mọ́lẹ̀ (2Sa 11:5, 14, 15; w19.09 17 ¶15)

Dáfídì jìyà ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ (2Sa 12:9-12; w18.06 17 ¶7)

Tá ò bá fẹ́ máa wo ìwòkuwò, tá ò sì fẹ́ kí èròkerò gbà wá lọ́kàn, a gbọ́dọ̀ máa kó ara wa níjàánu. (Ga 5:16, 22, 23) Jèhófà lè ràn wá lọ́wọ́ láti gbé èròkerò kúrò lọ́kàn wa.

BI ARA RẸ PÉ, ‘Irú àwọn èrò wo ló sábà máa ń wá sí mi lọ́kàn tó yẹ kí n ṣiṣẹ́ lé?’