June 20-26
2 SÁMÚẸ́LÌ 13-14
Orin 127 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Ámínónì Mọ Tara Ẹ̀ Nìkan, Ìyẹn sì Yọrí sí Àdánù Ńlá”: (10 min.)
Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)
2Sa 14:25, 26—Kí ni àpẹẹrẹ Ábúsálómù kọ́ wa nípa ẹwà tó ṣe pàtàkì jù? (g05 1/8 20-21)
Àwọn ìṣúra wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min.) 2Sa 14:8-20 (th ẹ̀kọ́ 2)
TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Fún ẹni náà ní ìtẹ̀jáde tó dáhùn ìbéèrè kan tó béèrè. (th ẹ̀kọ́ 12)
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Pe ẹni náà wá sípàdé. (th ẹ̀kọ́ 18)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min.) lff ẹ̀kọ́ 05 kókó 6 àti Àwọn Kan Sọ Pé (th ẹ̀kọ́ 18)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Fi Ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé! Ran Àwọn Èèyàn Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Nígbàgbọ́ Nínú Jèhófà àti Jésù”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo àwọn fídíò náà Fi Ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé! Ran Àwọn Èèyàn Lọ́wọ́ Kí Ìgbàgbọ́ Wọn Nínú Jèhófà Lè Lágbára! àti Fi Ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé! Ran Àwọn Èèyàn Lọ́wọ́ Kí Ìgbàgbọ́ Wọn Nínú Jésù Lè Lágbára!
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lff ẹ̀kọ́ 09
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 47 àti Àdúrà