Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Ámínónì Mọ Tara Ẹ̀ Nìkan, Ìyẹn sì Yọrí sí Àdánù Ńlá

Ámínónì Mọ Tara Ẹ̀ Nìkan, Ìyẹn sì Yọrí sí Àdánù Ńlá

Ọkàn Ámínónì fà sí Támárì (2Sa 13:1, 2; it-1 32)

Ámínónì fipá bá Támárì sùn (2Sa 13:10-15; w17.09 5 ¶11)

Ábúsálómù pa Ámínónì (2Sa 13:28, 29; it-1 33 ¶1)

Kí làwọn tó ń fẹ́ ara wọn sọ́nà lè ṣe tí wọn ò fi ní ṣèṣekúṣe? Wọ́n gbọ́dọ̀ máa kó ara wọn níjàánu, kí wọ́n sì yẹra fáwọn ipò tó lè mú kí wọ́n ṣèṣekúṣe.