June 27–July 3
2 SÁMÚẸ́LÌ 15-17
Orin 123 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Ìgbéraga Mú Kí Ábúsálómù Ṣọ̀tẹ̀”: (10 min.)
Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)
2Sa 16:4—Kí la rí kọ́ látinú bí Dáfídì ṣe kánjú ṣèpinnu? (w18.08 6 ¶11)
Àwọn ìṣúra wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min.) 2Sa 17:17-29 (th ẹ̀kọ́ 5)
TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Ẹni náà sọ ohun táwọn èèyàn sábà máa ń sọ tí wọn ò bá fẹ́ gbọ́ ìwàásù. Fèsì ní ṣókí, kó o sì máa bá ọ̀rọ̀ rẹ lọ. (th ẹ̀kọ́ 7)
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Ṣe bíi pé ẹ wo fídíò Báwo La Ṣe Máa Ń Ṣe Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì? (àmọ́ ẹ má ṣe wò ó) (th ẹ̀kọ́ 2)
Àsọyé: (5 min.) w09 5/15 27-28—Àkòrí: Máa Lo Ìtara Bíi Ti Ítáì Lẹ́nu Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ.—2Sa 15:19-22. (th ẹ̀kọ́ 13)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (5 min.)
“Ìfẹ́ . . . Kì Í Gbéra Ga”: (10 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Má Gbàgbé Ohun Tí Ìfẹ́ Máa Ń Ṣe—Kì Í Gbéra Ga.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lff ẹ̀kọ́ 10
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 87 àti Àdúrà