Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

June 6-12
  • Orin 124 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • Dáfídì Fi Ìfẹ́ Tí Kì Í Yẹ̀ Hàn”: (10 min.)

  • Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)

    • 2Sa 10:4, 5​—Kí nìdí tí ohun tí Hánúnì ṣe fi jẹ́ ohun ìtìjú fáwọn ọkùnrin Ísírẹ́lì? (it-1 266)

    • Àwọn ìṣúra wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min.) 2Sa 9:1-13 (th ẹ̀kọ́ 12)

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 116

  • Má Gbàgbé Ohun Tí Ìfẹ́ Máa Ń Ṣe​—Ó Ní Inú Rere: (5 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà. Lẹ́yìn náà, bi àwọn ará pé: Báwo ni Dáfídì ṣe fi inúure hàn sí Mefibóṣétì? Báwo la ṣe lè fi inúure àti ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ hàn sáwọn míì?

  • Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe: (10 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe ti oṣù June.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lff ẹ̀kọ́ 07

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)

  • Orin 1 àti Àdúrà