Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Ọgbọ́n Tí Dáfídì Dá Kó lè Dáàbò Bo Àwọn Èèyàn Ọlọ́run

Ọgbọ́n Tí Dáfídì Dá Kó lè Dáàbò Bo Àwọn Èèyàn Ọlọ́run

Dáfídì sá kí ọwọ́ Sọ́ọ̀lù má bàa tẹ̀ ẹ́ (1Sa 27:5-7; it-1 41)

Dáfídì dáàbò bo ààlà ilẹ̀ Júdà (1Sa 27:8, 9; w21.03 4 ¶8)

Dáfídì ò jẹ́ kí Ákíṣì mọ kúlẹ̀kúlẹ̀ ohun tí òun ń ṣe (1Sa 27:10-12; it-2 245 ¶6)

Lónìí, àwọn aláṣẹ lè fòfin de iṣẹ́ wa, kí wọ́n sì máa bi wá láwọn ìbéèrè tó lè ṣàkóbá fáwọn ará wa. Nírú àsìkò bẹ́ẹ̀, á dáa ká dákẹ́ jẹ́ẹ́ ká má bàa fi àwọn ará wa sínú ewu.​—Owe 10:19; 11:12; Onw 3:7.