May 23-29
2 SÁMÚẸ́LÌ 4-6
Orin 135 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Máa Ṣe Ohun Tí Jèhófà Fẹ́ Nígbà Gbogbo”: (10 min.)
Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)
2Sa 6:8, 9—Kí la rí kọ́ látinú bí Dáfídì ṣe hùwà pa dà nígbà tí inú bí Jèhófà? (w96 4/1 29 ¶1)
Àwọn ìṣúra wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min.) 2Sa 4:1-12 (th ẹ̀kọ́ 10)
TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Onílé sọ ohun táwọn èèyàn sábà máa ń sọ tí wọn ò bá fẹ́ gbọ́ ìwàásù. Fèsì ní ṣókí, kó o sì máa bá ọ̀rọ̀ rẹ lọ. (th ẹ̀kọ́ 12)
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Ṣe bíi pé ẹ wo fídíò Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì? (àmọ́ ẹ má ṣe wò ó) (th ẹ̀kọ́ 9)
Àsọyé: (5 min.) w05 10/1 23-24 ¶14-15 —Àkòrí: “Ẹ Bẹ̀rù Ọlọ́run, Kí Ẹ sì Fi Ògo Fún Un.”—Ifi 14:7. (th ẹ̀kọ́ 19)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Ṣé O Ti Múra Sílẹ̀ fún Rògbòdìyàn Tó Lè Ṣẹlẹ̀?”: (15 min.) Ìjíròrò. Alàgbà ni kó ṣe iṣẹ́ yìí. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ṣé O Ti Múra Sílẹ̀ De Àjálù? Mẹ́nu kan àwọn ìtọ́ni tí ẹ̀ka ọ́fíìsì ti fún un yín àtèyí tí ìgbìmọ̀ àwọn alàgbà fohùn ṣọ̀kan lé lórí, ìyẹn tó bá wà.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lff ẹ̀kọ́ 05
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 96 àti Àdúrà