Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Máa Ṣe Ohun Tí Jèhófà Fẹ́ Nígbà Gbogbo

Máa Ṣe Ohun Tí Jèhófà Fẹ́ Nígbà Gbogbo

Ti pé èèyàn ní èrò tó dáa kò túmọ̀ sí pé á ṣe nǹkan lọ́nà tí Jèhófà fẹ́ (2Sa 6:3-5; w05 5/15 17 ¶8)

Úsà rú Òfin Ọlọ́run (2Sa 6:6; w05 2/1 27 ¶20)

Jèhófà fìyà jẹ Úsà fún ohun tó ṣe (2Sa 6:7; w05 2/1 27 ¶21)

BI ARA RẸ PÉ, ‘Báwo ni mo ṣe lè fi hàn nínú ìgbésí ayé mi pé mi ò fẹ́ ba Jèhófà nínú jẹ́?’​—Owe 3:7