Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Gbára Lé Jèhófà Tó O Bá Ní Ẹ̀dùn Ọkàn

Gbára Lé Jèhófà Tó O Bá Ní Ẹ̀dùn Ọkàn

Àwọn ọmọ Ámálékì dáná sun Síkílágì, wọ́n sì kó àwọn tó wà níbẹ̀ lẹ́rú (1Sa 30:1, 2)

Ẹ̀dùn ọkàn bá Dáfídì àtàwọn ọkùnrin tó wà pẹ̀lú rẹ̀ (1Sa 30:3-5; w06 8/1 28 ¶12)

Dáfídì rí okun gbà látọ̀dọ̀ Jèhófà (1Sa 30:6; w12 4/15 30 ¶14)

RONÚ LÓRÍ ÌBÉÈRÈ YÌÍ: Ta ni mo máa ń gbára lé tí mo bá ní ẹ̀dùn ọkàn