Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

Nígbà Àkọ́kọ́ *

Ìbéèrè: Tá a bá wà nínú ìṣòro, kí ló jẹ́ ká mọ̀ pé Ọlọ́run kọ́ ló ń fìyà jẹ wá?

Bíbélì: Jem 1:13

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Kí nìdí tá a fi ń jìyà?

Ìpadàbẹ̀wò *

Ìbéèrè: Kí nìdí tá a fi ń jìyà?

Bíbélì: 1Jo 5:19

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Kí ló jẹ́ ká mọ̀ pé inú Ọlọ́run ò dùn sí ìyà tó ń jẹ wá?

^ ìpínrọ̀ 3 ^ ìpínrọ̀ 7 O lè lo ìbéèrè tàbí ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ míì tó bá ìpínlẹ̀ ìwàásù yín mu.