Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

NÍGBÀ ÀKỌ́KỌ́

Ìbéèrè: Àǹfààní wo la máa rí tá a bá ń ka Bíbélì?

Bíbélì: Ro 15:4

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Àwọn nǹkan wo ni Bíbélì sọ tó jẹ́ ká mọ̀ pé ọ̀la ń bọ̀ wá dáa?

ÌPADÀBẸ̀WÒ

Ìbéèrè: Àwọn nǹkan wo ni Bíbélì sọ tó jẹ́ ká mọ̀ pé ọ̀la ń bọ̀ wá dáa?

Bíbélì: Ifi 21:3, 4

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Kí la lè ṣe ká lè lóye ohun tó wà nínú Bíbélì?