June 12-18
2 KÍRÓNÍKÀ 32-33
Orin 103 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Máa Fún Àwọn Míì Níṣìírí Nígbà Ìṣòro”: (10 min.)
Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)
2Kr 33:15, 16—Kí la rí kọ́ lára Mánásè? (w21.10 4-5 ¶11-12)
Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min.) 2Kr 32:1-15 (th ẹ̀kọ́ 11)
TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (4 min.) Jíròrò ẹ̀yìn ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìbẹ̀rẹ̀ Ẹ̀kọ́ Bíbélì pẹ̀lú ẹni náà, kó o sì fi ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì lọ̀ ọ́. (th ẹ̀kọ́ 6)
Ìpadàbẹ̀wò: (3 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Fún ẹni náà ní ọ̀kan lára àwọn ìtẹ̀jáde tó wà nínú Àpótí Ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́. (th ẹ̀kọ́ 17)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min.) lff ẹ̀kọ́ 10 kókó 5 (th ẹ̀kọ́ 19)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Yẹra fún Ẹ̀kọ́ Àwọn Apẹ̀yìndà”: (10 min.) Ìjíròrò àti fídíò.
Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (5 min.)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lff ẹ̀kọ́ 48 kókó 1-4
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 90 àti Àdúrà