Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Máa Fún Àwọn Míì Níṣìírí Nígbà Ìṣòro

Máa Fún Àwọn Míì Níṣìírí Nígbà Ìṣòro

Senakérúbù gbógun ja ilẹ̀ Júdà, ó sì lérí pé òun máa gba Jerúsálẹ́mù (2Kr 32:1; it-1 204 ¶5)

Hẹsikáyà ṣe gbogbo ohun tó yẹ láti dáàbò bo Jerúsálẹ́mù (2Kr 32:2-5; w13 11/15 19 ¶12)

Hẹsikáyà fún àwọn èèyàn náà níṣìírí (2Kr 32:6-8; w13 11/15 19 ¶13)

BI ARA RẸ PÉ, ‘Báwo ni mo ṣe lè ran àwọn tá a jọ ń sin Jèhófà lọ́wọ́ nígbà ìṣòro?’