Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Jòsáyà fa aṣọ ẹ̀ ya nígbà tó gbọ́ ohun tí ìwé òfin Jèhófà sọ

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Ṣé Ò Ń Ṣiṣẹ́ Lórí Ohun Tí Ò Ń Kọ́ Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run?

Ṣé Ò Ń Ṣiṣẹ́ Lórí Ohun Tí Ò Ń Kọ́ Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run?

Jòsáyà fara balẹ̀ tẹ́tí sí Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run (2Kr 34:18, 19)

Ó ṣe gbogbo ohun tó lè ṣe kó lè lóye ohun tó gbọ́ nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run (2Kr 34:21; it-1 1157 ¶4; wo àwòrán iwájú ìwé)

Ó ṣiṣẹ́ lórí ohun tó gbọ́ (2Kr 34:33; w09 6/15 10 ¶20)

BI ARA RẸ PÉ, ‘Ṣé mo máa ń tètè ṣiṣẹ́ lórí ohun tí mo kà nípa Jèhófà nínú Bíbélì Ọ̀rọ̀ rẹ̀?’