Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Yọ̀ǹda Ara Ẹ fún Iṣẹ́ Jèhófà

Yọ̀ǹda Ara Ẹ fún Iṣẹ́ Jèhófà

[Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Ẹ́sírà.]

Jèhófà ta ẹ̀mí Ọba Kírúsì jí láti dá àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sílẹ̀ (Ẹsr 1:1-3; w22.03 14 ¶1)

Jèhófà ta ẹ̀mí àwọn èèyàn ẹ̀ jí kí wọ́n lè tún tẹ́ńpìlì tó wà ní Jerúsálẹ́mù kọ́ (Ẹsr 1:5; w17.10 26 ¶2)

Tó o bá yọ̀ǹda ara ẹ fún iṣẹ́ Jèhófà, ó máa lò ẹ́ láti mú ìfẹ́ ẹ̀ ṣẹ.