Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

June 5-11
  • Orin 87 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • Ó Dáa Ká Máa Lọ Sípàdé”: (10 min.)

  • Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)

    • 2Kr 30:20​—Kí la rí kọ́ látinú bí Jèhófà ṣe tẹ́tí sí Hẹsikáyà? (w18.09 6 ¶14-15)

    • Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min.) 2Kr 31:11-21 (th ẹ̀kọ́ 5)

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 74

  • Di Ọ̀rẹ́ Jèhófà​—Múra Ohun Tó O Máa Sọ ní Ìpàdé Sílẹ̀: (5 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ káwọn ará wo fídíò náà. Tó bá ṣeé ṣe bi àwọn ọmọdé pé: Báwo lo ṣe lè múra sílẹ̀ láti dáhùn nípàdé? Kí ló lè mú kí inú ẹ dùn tí wọn ò bá tiẹ̀ pè ẹ́ nípàdé?

  • Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe: (10 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe ti oṣù June.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lff ohun tó o kọ́ ní apá 3

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)

  • Orin 115 àti Àdúrà