Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Ó Dáa Ká Máa Lọ Sípàdé

Ó Dáa Ká Máa Lọ Sípàdé

Hẹsikáyà ṣètò Ìrékọjá tó ṣàrà ọ̀tọ̀ ní Jerúsálẹ́mù (2Kr 30:1; it-1 1103 ¶2)

Ọ̀pọ̀ èèyàn ló wá síbi àjọyọ̀ náà láìka àtakò sí (2Kr 30:10, 11, 13; it-1 1103 ¶3)

Ìdùnnú ṣubú layọ̀ ní Jerúsálẹ́mù, èyí sì mú kí wọ́n fọwọ́ pàtàkì mú ìjọsìn Jèhófà (2Kr 30:25–31:1; it-1 1103 ¶4-5)

BI ARA RẸ PÉ, ‘Àwọn àǹfààní wo ni mo ti rí bí mo ṣe ń lọ sáwọn ìpàdé àti àpéjọ lójúkojú bí ò tiẹ̀ rọrùn?’