May 1-7
2 KÍRÓNÍKÀ 17-19
Orin 114 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Máa Fi Ojú Tí Jèhófà Fi Ń Wo Àwọn Èèyàn Wò Wọ́n”: (10 min.)
Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)
2Kr 17:9—Kí la rí kọ́ nínú bí Jèhóṣáfátì ṣe ṣètò pé kí wọ́n kọ́ àwọn èèyàn ní òfin Jèhófà? (w17.03 20 ¶10-11)
Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min.) 2Kr 17:1-19 (th ẹ̀kọ́ 11)
TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Fídíò Nígbà Àkọ́kọ́: (5 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ káwọn ará wo fídíò Nígbà Àkọ́kọ́: Bíbélì—Ro 15:4. Ẹ dá fídíò náà dúró láwọn ibi tẹ́ ẹ bá ti rí ìbéèrè, kẹ́ ẹ sì dáhùn àwọn ìbéèrè náà kẹ́ ẹ tó máa wò ó lọ.
Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o lò. (th ẹ̀kọ́ 18)
Àsọyé: (5 min.) w21.05 17-18 ¶11-15—Àkòrí: Má Jẹ́ Kó Sú Ẹ Táwọn Èèyàn Ò Bá Fẹ́ Gbọ́ Ìwàásù. (th ẹ̀kọ́ 16)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Ojú Tí Jèhófà Fi Ń Wò Ẹ́ Ni Kó O Fi Máa Wo Ara Ẹ”: (15 min.) Ìjíròrò àti fídíò.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lff ẹ̀kọ́ 44 kókó 5-6 àti kókó pàtàkì, kí lo rí kọ́? àti ohun tó yẹ kó o ṣe
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 111 àti Àdúrà