Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

“Jèhófà Mọ Bó Ṣe Máa Fi Èyí Tó Pọ̀ Ju Bẹ́ẹ̀ San Án Fún Ọ”

“Jèhófà Mọ Bó Ṣe Máa Fi Èyí Tó Pọ̀ Ju Bẹ́ẹ̀ San Án Fún Ọ”

Amasááyà háyà àwọn ọmọ ogun nígbà tó fẹ́ bá àwọn ọ̀tá Ọlọ́run jà (2Kr 25:5, 6)

Èèyàn Ọlọ́run kan sọ fún Amasááyà pé kó ní káwọn ọmọ ogun tó háyà náà pa dà sílé (2Kr 25:7, 8; it-1 1266 ¶6)

Jèhófà lè fún Amasááyà ní ọrọ̀ tó pọ̀ ju ohun tó pàdánù lọ (2Kr 25:9, 10)

BI ARA RẸ PÉ: ‘Àwọn nǹkan wo ni mo lè yááfì kí n lè ṣe púpọ̀ sí i fún Jèhófà? Àwọn àǹfààní wo ni mo máa rí tí mo bá ṣe bẹ́ẹ̀?’​—Mal 3:10; w21.08 30 ¶16.