Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

O Lè Sin Jèhófà Táwọn Òbí Ẹ Ò Bá Tiẹ̀ Ṣe Bẹ́ẹ̀

O Lè Sin Jèhófà Táwọn Òbí Ẹ Ò Bá Tiẹ̀ Ṣe Bẹ́ẹ̀

Ọba Áhásì bàbá Hẹsikáyà ṣe ohun tó burú gan-an lojú Jèhófà (2Kr 28:1; w16.02 10 ¶8)

Hẹsikáyà pinnu láti sin Jèhófà bó tiẹ̀ jẹ́ pé bàbá ẹ̀ jẹ́ abọ̀rìṣà (2Kr 29:1-3; w16.02 11 ¶9-11)

Hẹsikáyà fún àwọn míì níṣìírí pé kí wọ́n má ṣíwọ́ láti máa sin Jèhófà, bó tiẹ̀ jẹ́ pé àwọn bàbá wọn ò sin Jèhófà (2Kr 29:4-6)

BI ARA RẸ PÉ, ‘Àwọn nǹkan wo ni mo lè ṣe tó máa fún àwọn ọ̀dọ́ táwọn òbí wọn ò sin Jèhófà níṣìírí láti máa sin Jèhófà nìṣó?’