November 14 sí 20
Oníwàásù 1-6
Orin 66 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Gbádùn Gbogbo Iṣẹ́ Àṣekára Rẹ”: (10 min.)
[Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò tá a pe àkọlé rẹ̀ ní Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Oníwàásù.]
Onw 3:12, 13
—Iṣẹ́ àṣekára jẹ́ ẹ̀bùn látọ̀dọ̀ Ọlọ́run, ó sì yẹ ká gbádùn rẹ̀ (w15 2/1 ojú ìwé 4 sí 6) Onw 4:6
—Máa fi ojú tó tọ́ wo iṣẹ́ rẹ (w15 2/1 ojú ìwé 6 ìpínrọ̀ 3 sí 5)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Onw 2:10, 11
—Kí ni Sólómọ́nì wá mọ̀ nípa níní ọrọ̀? (w08 4/15 ojú ìwé 22 ìpínrọ̀ 9 àti 10) Onw 3:16, 17
—Ojú wo ló yẹ ká máa fi wo ìwà ìrẹ́jẹ tó kúnnú ayé? (w06 11/1 ojú ìwé 14 ìpínrọ̀ 9) Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?
Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Onw 1:1-18
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Àwòrán iwájú ìwé ìròyìn wp16.6 tó wà lójú ìwé 2
—Fún un ní káàdì ìkànnì JW.ORG. Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Kókó iwájú ìwé ìròyìn wp16.6
—Ka ẹsẹ Bíbélì kan látorí fóònù tàbí tablet. Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh ojú ìwé 22 àti 23 ìpínrọ̀ 11 àti 12
—Pe ẹni náà wá sí ìpàdé.
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Bá A Ṣe Máa Lo Ìwé Kí Ni Bíbélì Kọ́ Wa? ”: (15 min.) Ìjíròrò. Lẹ́yìn náà, jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò bá a ṣe ń darí ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì, tó dá lórí Òtítọ́ 4 lójú ìwé 115 nínú ìwé Bíbélì Kọ́ Wa, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr orí 4 ìpínrọ̀ 1 sí 6, àpótí náà “Ìtumọ̀ Orúkọ Ọlọ́run”
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 112 àti Àdúrà