November 21 sí 27
ONÍWÀÁSÙ 7-12
Orin 41 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Rántí Ẹlẹ́dàá Rẹ Atóbilọ́lá . . . Ní Àwọn Ọjọ́ Tí O Wà Ní Ọ̀dọ́kùnrin”: (10 min.)
Onw 12:1
—Ó yẹ kí àwọn ọ̀dọ́ lo àkókò àti okun wọn lẹ́nu iṣẹ́ ìsìn Ọlọ́run (w14 1/15 ojú ìwé 18 ìpínrọ̀ 3 àti ojú ìwé 22 ìpínrọ̀ 1) Onw 12:2-7
—“Àwọn ọjọ́ oníyọnu àjálù” tó máa ń dé bá àwọn arúgbó kì í dí àwọn ọ̀dọ́ lọ́wọ́ (w08 11/15 ojú ìwé 23 ìpínrọ̀ 2; w06 11/1 ojú ìwé 16 ìpínrọ̀ 10) Onw 12:13, 14
—Sísin Jèhófà nìkan ló lè mú kí ìgbésí ayé rẹ dára (w11 11/1 ojú ìwé 21 ìpínrọ̀ 1 sí 6)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Onw 10:12–11:10
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 2Ti 3:
1-5 —Máa Fi Òtítọ́ Kọ́ni. Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ais 44:27–45:2
—Máa Fi Òtítọ́ Kọ́ni. Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh ojú ìwé 25 àti 26 ìpínrọ̀ 18 sí 20
—Pe akẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì náà wá sí ìpàdé.
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Orin 95
“Ẹ̀yin Ọ̀dọ́
—Ẹ Má Ṣe Fàkókò Ṣòfò Láti Wọnú ‘Ilẹ̀kùn Ńlá’”: (15 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò tá a pe àkọlé rẹ̀ ní Ẹ̀yin Ọ̀dọ́ —Jèhófà Nífẹ̀ẹ́ Yín, kẹ́ ẹ sì jíròrò àpilẹ̀kọ náà. Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr orí 4 ìpínrọ̀ 7 sí 15, àti àpótí náà “Bí Ilé Ìṣọ́ Ṣe Ti Ń Gbé Orúkọ Ọlọ́run Lékè,” àti àpótí náà “Ìdí Pàtàkì Tó Fi Yẹ Ká Máa Wàásù”
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 148 àti Àdúrà
Ìránnilétí: Jẹ́ kí àwọn ará kọ́kọ́ gbọ́ orin tuntun yìí lẹ́ẹ̀kan, lẹ́yìn náà, kí ẹ kọ ọ́.