November 28 sí December 4
ORIN SÓLÓMỌ́NÌ 1-8
Orin 106 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Ọmọbìnrin Ṣúlámáítì Jẹ́ Àpẹẹrẹ Rere Tá A Lè Tẹ̀ Lé”: (10 min.)
[Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò tá a pe àkọlé rẹ̀ ní Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Orin Sólómọ́nì.]
Sol 2:7; 3:5
—Ọmọbìnrin Ṣúlámáítì pinnu láti dúró dìgbà táá fi rí ẹni tó máa nífẹ̀ẹ́ tọkàntọkàn (w15 1/15 ojú ìwé 31 ìpínrọ̀ 11 sí 13) Sol 4:12; 8:8-10
—Ní gbogbo àkókò tó fi dúró, ó jẹ́ adúróṣinṣin àti oníwà mímọ́ (w15 1/15 ojú ìwé 31 àti 32 ìpínrọ̀ 14 sí 16)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Sol 2:1
—Ànímọ́ wo ló gbé ẹwà Ṣúlámáítì yọ dáadáa? (w15 1/15 ojú ìwé 31 ìpínrọ̀ 13) Sol 8:6
—Kí nìdí tí Bíbélì fi pe ìfẹ́ tòótọ́ ní “ọwọ́ iná Jáà”? (w15 1/15 ojú ìwé 29 ìpínrọ̀ 3; w06 11/15 ojú ìwé 20 ìpínrọ̀ 7) Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?
Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Sol 2:1-17
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh
—Lo fídíò Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì? láti fi nasẹ̀ ìwé náà. (Àkíyèsí: Ẹ má ṣe wo fídíò yìí nígbà àṣefihàn náà.) Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh
—Pe ẹni náà wá sí ìpàdé. Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh ojú ìwé 30 àti 31 ìpínrọ̀ 8 àti 9
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Orin 115
“Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé
—Ṣó Ti Yẹ Kí N Lẹ́ni Tí Mò Ń Fẹ́?”: (9 min.) Àsọyé tó dá lórí àpilẹ̀kọ tá a pè àkòrí rẹ̀ ní “Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé —Ṣó Ti Yẹ Kí N Lẹ́ni Tí Mò Ń Fẹ́?” Ṣé Ìfẹ́ Tòótọ́ Ni àbí Ìfẹ́ Ojú Lásán?: (6 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò eré ojú pátákó tá a pe àkọlé rẹ̀ ní, Ṣé Ìfẹ́ Tòótọ́ Ni àbí Ìfẹ́ Ojú Lásán? kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr orí 4 ìpínrọ̀ 16 sí 23, pótí náà “Ṣé O Gbà Lóòótọ́ Pé Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso?”
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 34 àti Àdúrà