November 7 sí 13
ÒWE 27-31
Orin 86 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Bíbélì Sọ Ohun Tí Ìyàwó Tó Dáńgájíá Máa Ń Ṣe”: (10 min.)
Owe 31:10-12
—Ó jẹ́ ẹni tó ṣe é fọkàn tán (w15 1/15 ojú ìwé 20 ìpínrọ̀ 10; w00 2/1 ojú ìwé 31 ìpínrọ̀ 2; it-2-E ojú ìwé 1183 ìpínrọ̀ 6) Owe 31:13-27
—Ó jẹ́ òṣìṣẹ́ kára (w00 2/1 ojú ìwé 31 ìpínrọ̀ 3 àti 4) Owe 31:28-31
—Ó jẹ́ ẹni tí òtítọ́ jinlẹ̀ nínú rẹ̀, tó yẹ kéèyàn máa gbóríyìn fún (w15 1/15 ojú ìwé 20 ìpínrọ̀ 8; w00 2/1 ojú ìwé 31 ìpínrọ̀ 5 àti 8)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Owe 27:12
—Báwo la ṣe lè fi hàn pé a gbọ́n tó bá dọ̀rọ̀ eré ìnàjú? (w15 7/1 ojú ìwé 8 ìpínrọ̀ 3) Owe 27:21
—Kí ni ìtumọ̀ gbólóhùn náà, “ẹnì kọ̀ọ̀kan wà ní ìbámu pẹ̀lú ìyìn rẹ̀”? (w11 8/1 ojú ìwé 29 ìpínrọ̀ 1; w06 9/15 ojú ìwé 19 ìpínrọ̀ 11) Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?
Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Owe 29:11–30:4
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Múra Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Oṣù Yìí Sílẹ̀: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn fídíò ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀, kẹ́ ẹ sì jíròrò àwọn kókó pàtàkì látinú àwọn fídíò náà. Gba àwọn ará níyànjú láti kọ ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ wọn sílẹ̀.
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Orin 89
“Ẹni Mímọ̀ Ni Ọkọ Rẹ̀ Jẹ́ Ní Àwọn Ẹnubodè”: (5 min.) Alàgbà ni kó sọ àsọyé yìí.
Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (10 min.) Ẹ sì lè jíròrò ẹ̀kọ́ tá a rí kọ́ nínú Ìwé Ọdọọdún. (yb16 ojú ìwé 40 àti 41)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr orí 3 ìpínrọ̀ 13 sí 22, àti “Jèhófà Ń Ṣí Ète Rẹ̀ Payá Ní Ṣísẹ̀-N-Tẹ̀lé,” àpótí náà “Ṣé O Gbà Lóòótọ́ Pé Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso?”
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 108 àti Àdúrà