November 18-24
ÌFIHÀN 1-3
Orin 15 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Mo Mọ Àwọn Iṣẹ́ Rẹ”: (10 min.)
[Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Ìfihàn.]
Ifi 1:20—Jésù ló ń darí gbogbo ìgbìmọ̀ àwọn alàgbà (w12 10/15 14 ¶8)
Ifi 2:1, 2—Jésù mọ ohun tó ń ṣẹlẹ̀ ní gbogbo ìjọ (w12 4/15 29 ¶11; w01 1/15 20-21 ¶20)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Ifi 1:7—Báwo ni gbogbo ojú ṣe máa rí Jésù bó ṣe “ń bọ̀ pẹ̀lú ìkùukùu,” ìgbà wo nìyẹn sì máa ṣẹlẹ̀? (kr 226 ¶10)
Ifi 2:7—Kí ni jíjẹ nínú “igi ìyè” ní “párádísè Ọlọ́run” túmọ̀ sí? (w09 1/15 31 ¶1)
Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ifi 1:1-11 (th ẹ̀kọ́ 5)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́—Fídíò: (5 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.
Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. (th ẹ̀kọ́ 2)
Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. Ṣe bíi pé ẹ wo fídíò Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì? (àmọ́ ẹ má ṣe wò ó) lẹ́yìn náà, kẹ́ ẹ jíròrò rẹ̀ (th ẹ̀kọ́ 3)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Jèhófà Mọ Ohun Tá A Nílò”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ìròyìn Iṣẹ́ Ìgbìmọ̀ Ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́—2017.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 12 ¶20-22
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 151 àti Àdúrà