November 4-10
1 JÒHÁNÙ 1-5
Orin 122 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Ẹ Má Ṣe Nífẹ̀ẹ́ Ayé Tàbí Àwọn Nǹkan Tó Wà Nínú Ayé”: (10 min.)
[Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Jòhánù Kìíní.]
1Jo 2:15, 16—‘Gbogbo ohun tó wà nínú ayé wá látọ̀dọ̀ ayé,’ kì í ṣe látọ̀dọ̀ Baba (w05 1/1 10 ¶13)
1Jo 2:17—Ayé àti ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ rẹ̀ ń kọjá lọ (w13 8/15 27 ¶18)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
1Jo 2:7, 8—Báwo ni àṣẹ tí Jòhánù tọ́ka sí ṣe jẹ́ àṣẹ àtijọ́, tó sì tún jẹ́ tuntun? (w13 9/15 10 ¶14)
1Jo 5:16, 17—Kí ni ‘ẹ̀ṣẹ̀ tó yẹ fún ikú’? (it-1 862 ¶5)
Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 1Jo 1:1–2:6 (th ẹ̀kọ́ 5)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Tẹra Mọ́ Kíkàwé àti Kíkọ́ni: (10 min.) Ìjíròrò. Ẹ wo fídíò Ìtara, lẹ́yìn náà, ẹ jíròrò ẹ̀kọ́ 11 nínú ìwé pẹlẹbẹ Kíkọ́ni.
Àsọyé: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) w04 10/1 29—Àkòrí: Bó ṣe wà nínú 1 Jòhánù 4:18, kí ni Jòhánù ní lọ́kàn nígbà tó sọ pé “ìfẹ́ tó pé máa ń lé ìbẹ̀rù jáde”? (th ẹ̀kọ́ 7)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Yẹra fún Ẹ̀mí Ayé Tó O Bá Ń Ṣètò Ìgbéyàwó”: (15 min.) Ìjíròrò. Ẹ wo fídíò Ìgbéyàwó Tó Ní Ọlá Lójú Jèhófà.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 12 ¶10-16
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 118 àti Àdúrà