November 23-29
LÉFÍTÍKÙ 6-7
Orin 46 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Ohun Tá A Mú Wá Láti Dúpẹ́”: (10 min.)
Le 7:11, 12—Ẹbọ ìrẹ́pọ̀ jẹ́ ẹbọ táwọn èèyàn máa ń rú láti dúpẹ́ lọ́wọ́ Jèhófà (w19.11 22 ¶9)
Le 7:13-15—Lọ́nà ìṣàpẹẹrẹ, ẹni tó ń rú ẹbọ náà àti ìdílé rẹ̀ ń jẹun pẹ̀lú Jèhófà, ìyẹn sì fi hàn pé wọ́n ní àjọṣe tó dáa pẹ̀lú rẹ̀ (w00 8/15 15 ¶15)
Le 7:20—Kí Jèhófà tó lè tẹ́wọ́ gba ẹbọ ìrẹ́pọ̀ ẹnì kan, ẹni náà gbọ́dọ̀ jẹ́ mímọ́ (w00 8/15 19 ¶8)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (10 min.)
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Le 6:1-18 (th ẹ̀kọ́ 5)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Sọ̀rọ̀ lórí kókó kan látinú Ilé Ìṣọ́ No. 2 2020, kó o sì fún onílé ní ìwé ìròyìn náà. (th ẹ̀kọ́ 3)
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Ní kí onílé lọ sórí ìkànnì wa, kó o sì fún un ní káàdì ìkànnì jw.org. (th ẹ̀kọ́ 11)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bhs 178-179 ¶12-13 (th ẹ̀kọ́ 6)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Di Ọ̀rẹ́ Jèhófà—Jẹ́ Ẹni Tó Moore: (5 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà. Lẹ́yìn náà, pe àwọn ọmọdé bíi mélòó kan wá sórí pèpéle, kó o sì bi wọ́n ní ìbéèrè nípa fídíò náà.
Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (10 min.)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) rr orí 1 ¶1-7 àti fídíò ohun tó wà ní orí 1 *
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
Orin 37 àti Àdúrà
^ ìpínrọ̀ 23 Orí kọ̀ọ̀kan ìwé yìí ló ní fídíò, ẹ kọ́kọ́ wo fídíò yìí kẹ́ ẹ tó bẹ̀rẹ̀ sí í jíròrò orí náà.