November 30–December 6
LÉFÍTÍKÙ 8-9
Orin 16 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Ẹ̀rí Tó Fi Hàn Pé Jèhófà Tẹ́wọ́ Gbà Wọ́n”: (10 min.)
Le 8:6-9, 12—Mósè yan àwọn àlùfáà (it-1 1207)
Le 9:1-5—Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì wà níbẹ̀ nígbà táwọn àlùfáà rú ẹbọ àkọ́kọ́ (it-1 1208 ¶8)
Le 9:23, 24—Jèhófà jẹ́ kí wọ́n rí i pé òun tẹ́wọ́ gba àwọn àlùfáà náà (w19.11 23 ¶13)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (10 min.)
Le 8:6—Kí la rí kọ́ nínú bí Jèhófà ṣe fún àwọn àlùfáà lófin pé wọ́n gbọ́dọ̀ wà ní mímọ́ tónítóní? (w14 11/15 9 ¶6)
Le 8:14-17—Nígbà tí wọ́n yan àwọn àlùfáà, kí nìdí tó fi jẹ́ pé Mósè ló rú ẹbọ tí kì í ṣe Áárónì? (it-2 437 ¶3)
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Le 8:31–9:7 (th ẹ̀kọ́ 5)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Sọ̀rọ̀ lórí kókó kan látinú Ilé Ìṣọ́ No. 2 2020, kó o sì fún onílé ní ìwé ìròyìn náà. (th ẹ̀kọ́ 6)
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Ní kí onílé lọ sórí ìkànnì wa, kó o sì fún un ní káàdì ìkànnì jw.org. (th ẹ̀kọ́ 4)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bhs 84 ¶6-7 (th ẹ̀kọ́ 11)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Mú Kí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Sunwọ̀n Sí I—Máa Fi Tẹlifóònù Wàásù”: (15 min.) Alábòójútó iṣẹ́ ìsìn ni kó bójú tó apá yìí. Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) rr orí 1 ¶8-14 àti àpótí 1A
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
Orin 40 àti Àdúrà