Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
●○ NÍGBÀ ÀKỌ́KỌ́
Ìbéèrè: Kí ni Ìjọba Ọlọ́run?
Bíbélì: Mt 6:9, 10 tàbí Ais 9:6, 7
Ìbéèrè fún ìgbà míì: Kí Ni Ìjọba Ọlọ́run Máa Ṣe?
○● ÌPADÀBẸ̀WÒ
Ìbéèrè: Kí Ni Ìjọba Ọlọ́run Máa Ṣe?
Bíbélì: Mt 14:19, 20 tàbí Sm 72:16
Ìbéèrè fún ìgbà míì: Ìgbà Wo Ni Ìjọba Ọlọ́run Máa Ṣàkóso Ayé?