ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Lọ Lo Agbára Tí O Ní”
Jèhófà ní kí Gídíónì ṣe iṣẹ́ kan tó nira láti ṣe (Ond 6:2-6, 14)
Gídíónì gbà pé òun ò já mọ́ nǹkan kan àti pé iṣẹ́ náà ò tọ́ sóun (Ond 6:15; w02 2/15 6 ¶5)
Jèhófà ran Gídíónì lọ́wọ́ kó lè ṣàṣeyọrí lẹ́nu iṣẹ́ náà (Ond 7:19-22; w05 7/15 16 ¶3)
Jèhófà fẹ́ ká fi gbogbo okun wa jọ́sìn òun. Tó bá ń ṣe wá bíi pé a ò lókun mọ́, ẹ̀mí mímọ́ Jèhófà máa ràn wá lọ́wọ́ ká lè ṣàṣeyọrí.—Ais 40:30, 31.