ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
Ìmọ̀ràn Tí Jóṣúà Fún Àwọn Ọmọ Ísírẹ́lì Kẹ́yìn
‘Ẹ máa ṣọ́ra ní gbogbo ìgbà, kí ẹ sì máa nífẹ̀ẹ́ Jèhófà’ (Joṣ 23:11)
Ẹ má ṣe bá àwọn orílẹ̀-èdè náà da nǹkan pọ̀ (Joṣ 23:12, 13; it-1 75)
Ẹ gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà (Joṣ 23:14; w07 11/1 26 ¶19-20)
Tá a bá ń tẹ̀ lé ìmọ̀ràn tí Jóṣúà fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, báwo nìyẹn ṣe lè mú ká jẹ́ adúróṣinṣin sí Jèhófà?