ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
Ìtàn Tó Ń Mórí Ẹni Wú Nípa Ọkùnrin Onígboyà Kan
[Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Àwọn Onídàájọ́.]
Jèhófà yan Éhúdù láti gba àwọn ọmọ Ísírẹ́lì lọ́wọ́ àwọn ará Móábù (Ond 3:15; w04 3/15 31 ¶3)
Éhúdù pa ọba Ẹ́gílónì, ìyẹn sì mú káwọn ọmọ Ísírẹ́lì ṣẹ́gun àwọn ará Móábù (Ond 3:16-23, 30; w04 3/15 30 ¶1-3)
Kí ni ìtàn yìí kọ́ wa nípa ìdí tó fi yẹ ká jẹ́ onígboyà, ká sì gbára lé Jèhófà?