December 19-25
2 ÀWỌN ỌBA 18-19
Orin 148 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Ọgbọ́n Táwọn Alátakò Máa Ń Dá Kí Wọ́n Lè Kó Ìrẹ̀wẹ̀sì Bá Wa”: (10 min.)
Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)
2Ọb 19:37—Báwo ni ẹsẹ Bíbélì yìí ṣe jẹ́ ká rí i pé ó ṣe pàtàkì ká gbé ìwádìí àwọn awalẹ̀pìtàn yẹ̀ wò dáadáa ká tó gbà á gbọ́? (it-1 155 ¶4)
Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min.) 2Ọb 18:1-12 (th ẹ̀kọ́ 5)
TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Pe ẹni náà wá sípàdé, kó o sì ṣe bíi pé ẹ wo fídíò Kí Ló Máa Ń Ṣẹlẹ̀ Nínú Gbọ̀ngàn Ìjọba? (àmọ́ ẹ má ṣe wò ó) (th ẹ̀kọ́ 1)
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Ṣàlàyé bá a ṣe máa ń kọ́ àwọn èèyàn lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì lọ́fẹ̀ẹ́, kó o sì fún un ní káàdì ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì. (th ẹ̀kọ́ 2)
Àsọyé: (5 min.) w20.11 15 ¶14—Àkòrí: Máa Gbàdúrà Fáwọn Tí Wọ́n Ń Ṣe Inúnibíni Sí (th ẹ̀kọ́ 14)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Ẹ Máa Yọ̀ Tẹ́ Ẹ Bá Ń Dojú Kọ Inúnibíni”: (8 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò A Lè Láyọ̀ Bá A Tiẹ̀ Ń Dojú Kọ Inúnibíni.
Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (7 min.)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lff ẹ̀kọ́ 32 kókó 1-4 àti àtẹ “Ohun Tí Àlá Nípa Igi Náà Jẹ́ Ká Mọ̀ Nípa Ìjọba Ọlọ́run”
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 22 àti Àdúrà