December 26, 2022–January 1, 2023
2 ÀWỌN ỌBA 20-21
Orin 41 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Àdúrà Mú Kí Jèhófà Gbé Ìgbésẹ̀”: (10 min.)
Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)
2Ọb 21:13—Ọ̀nà wo ni Jèhófà gbà fi irinṣẹ́ tí a fi ń mú nǹkan tẹ́jú díwọ̀n Jerúsálẹ́mù? (it-2 240 ¶1)
Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min.) 2Ọb 21:1-15 (th ẹ̀kọ́ 10)
TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Onílé sọ ohun táwọn èèyàn sábà máa ń sọ tí wọn ò bá fẹ́ gbọ́ ìwàásù. Fèsì ní ṣókí, kó o sì máa bá ọ̀rọ̀ rẹ lọ. (th ẹ̀kọ́ 4)
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Sọ fún ẹni náà nípa ìkànnì wa, kó o sì fún un ní káàdì ìkànnì jw.org. (th ẹ̀kọ́ 6)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min.) lff ẹ̀kọ́ 08 kókó 6 (th ẹ̀kọ́ 19)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Àdúrà Wa Ṣeyebíye Lójú Jèhófà”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ káwọn ará wo fídíò Mi Ò Fọ̀rọ̀ Àdúrà Ṣeré.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lff ẹ̀kọ́ 32 kókó 5-6, kí lo rí kọ́? àti ohun tó yẹ kó o ṣe
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 142 àti Àdúrà