Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Ó Nígboyà, Ó sì Fìtara Jíṣẹ́ Tí Jèhófà Rán An Láìfi Falẹ̀

Ó Nígboyà, Ó sì Fìtara Jíṣẹ́ Tí Jèhófà Rán An Láìfi Falẹ̀

Jèhófà sọ fún Jéhù pé kó lọ pa àwọn ará ilé Áhábù tó jẹ́ ọba búburú run (2Ọb 9:6, 7; w11 11/15 3 ¶2)

Jéhù gbé ìgbésẹ̀ láìjáfara, ó sì pa Ọba Jèhórámù (ìyẹn ọmọ Áhábù) àti Ayaba Jésíbẹ́lì (ìyẹn ìyàwó Áhábù) (2Ọb 9:22-24, 30-33; w11 11/15 4 ¶2-3; wo àtẹ náà “‘Gbogbo Ilé Áhábù Ló Máa Ṣègbé’​—2Ọb 9:8”)

Jéhù lo ìgboyà, ó sì fìtara jíṣẹ́ tí Jèhófà rán an láìfi falẹ̀ (2Ọb 10:17; w11 11/15 5 ¶3-4)

BI ARA RẸ PÉ, ‘Báwo ni mo ṣe lè fara wé Jéhù tó bá di pé kí n tẹ̀ lé àṣe tó wà nínú Mátíù 28:19, 20?’