Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Jèhófà Fìyà Jẹ Obìnrin Burúkú Kan

Jèhófà Fìyà Jẹ Obìnrin Burúkú Kan

Ataláyà pa àwọn ọmọ ọba kó lè máa ṣàkóso ilẹ̀ Júdà (2Ọb 11:1; it-1 209; wo àtẹ náà “‘Gbogbo Ilé Áhábù Ló Máa Ṣègbé’​—2Ọb 9:8”)

Jèhóṣébà gbé Jèhóáṣì tó jẹ́ ọmọ ọba pa mọ́ (2Ọb 11:2, 3)

Jèhóádà Àlùfáà Àgbà fi Jèhóáṣì jọba, ó sì pa Ataláyà tó ṣeé ṣe kó jẹ́ ẹnì kan ṣoṣo tó ṣẹ́ kù nílé Áhábù (2Ọb 11:12-16; it-1 209)

ṢÀṢÀRÒ LÓRÍ ÌBÉÈRÈ YÌÍ: Báwo ni ìtàn yìí ṣe jẹ́ kó túbọ̀ dá wa lójú pé òótọ́ lohun tó wà ní Òwe 11:21 àti Oníwàásù 8:12, 13?