Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Kò Dìgbà Tá A Bá Jẹ́ Ẹni Pípé Ká Tó Lè Jẹ́ Olóòótọ́

Kò Dìgbà Tá A Bá Jẹ́ Ẹni Pípé Ká Tó Lè Jẹ́ Olóòótọ́

Jóòbù dá Ọlọ́run lẹ́bi láìmọ̀ (Job 27:​1, 2)

Bó tiẹ̀ jẹ́ pé Jóòbù ṣe àwọn àṣìṣe kan, ó gbà pé òun jẹ́ olóòótọ́ sí Ọlọ́run (Job 27:5; it-1 1210 ¶4)

Kò dìgbà tá a bá jẹ́ ẹni pípé ká tó lè jẹ́ olóòótọ́, tá a bá ti nífẹ̀ẹ́ Jèhófà tọkàntọkàn, Jèhófà máa kà wá sí olóòótọ́ (Mt 22:37; w19.02 3 ¶3-5)

RONÚ LÓRÍ ÌBÉÈRÈ YÌÍ: Bá a ṣe mọ̀ pé Jèhófà ò retí pé ká jẹ́ ẹni pípé, ṣé ó yẹ ká máa ro ara wa pin tá a bá ṣàṣìṣe?