December 25-31
JÓÒBÙ 30-31
Orin 28 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Bí Jóòbù Ṣe Fi Hàn Pé Òun Jẹ́ Oníwà Mímọ́”: (10 min.)
Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)
Job 31:35—Kí la lè ṣe tá ò fi ní dà bí àwọn ọ̀rẹ́ Jóòbù tẹ́nì kan bá ń sọ ohun tó ń dùn ún fún wa? (w05 11/15 11 ¶3)
Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min.) Job 31:15-40 (th ẹ̀kọ́ 5)
TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (4 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Ṣàlàyé bá a ṣe máa ń kọ́ àwọn èèyàn lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì, kó o sì fún un ní káàdì ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì. (th ẹ̀kọ́ 1)
Ìpadàbẹ̀wò: (3 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Pe ẹni náà wá sípàdé, kó o sì ṣe bíi pé ẹ wo fídíò Kí Ló Máa Ń Ṣẹlẹ̀ Nínú Gbọ̀ngàn Ìjọba? kẹ́ ẹ sì jíròrò ẹ̀ (àmọ́ ẹ má ṣe wò ó). (th ẹ̀kọ́ 11)
Àsọyé: (5 min.) g16.4 8-9—Àkòrí: Báwo Ni Mo Ṣe Lè Ṣàlàyé Ohun Tí Bíbélì Sọ Nípa Ìbẹ́yà-Kan-Náà-Lòpọ̀? (th ẹ̀kọ́ 14)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Kí Nìdí Tí Wíwo Àwòrán Ìṣekúṣe Fi Burú?”: (7 min.) Ìjíròrò àti fídíò.
Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (8 min.)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bt orí 4 ¶1-8
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 74 àti Àdúrà