Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Bí Jóòbù Ṣe Fi Hàn Pé Òun Jẹ́ Oníwà Mímọ́

Bí Jóòbù Ṣe Fi Hàn Pé Òun Jẹ́ Oníwà Mímọ́

Jóòbù bá ojú rẹ̀ dá májẹ̀mú (Job 31:1; w10 4/15 21 ¶8)

Jóòbù ronú lórí ohun tó máa jẹ́ àbájáde ìwà tí ò dáa (Job 31:​2, 3; w08 9/1 11 ¶4)

Jóòbù fi sọ́kàn pé Ọlọ́run ń rí gbogbo ohun tóun ń ṣe (Job 31:4; w10 11/15 5-6 ¶15-16)

Ká jẹ́ mímọ́ kọjá pé ká kàn mọ́ lóde ara nìkan, ó tún kan irú ẹni tá a jẹ́ ní inú. Kódà, a gbọ́dọ̀ sapá láti gbé èròkerò kúrò lọ́kàn wa.—Mt 5:28.