Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

December 4-10

JÓÒBÙ 22-24

December 4-10
  • Orin 49 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • Ṣé Èèyàn Wúlò fún Ọlọ́run?”: (10 min.)

  • Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)

    • Job 23:13—Báwo ni àpẹẹrẹ Jèhófà ṣe lè ràn wá lọ́wọ́ kọ́wọ́ wa lè tẹ àwọn ohun tá a pinnu láti ṣe lẹ́nu iṣẹ́ ìsìn rẹ̀? (w04 7/15 21-22)

    • Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min.) Job 22:​1-22 (th ẹ̀kọ́ 5)

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI